Angelique Kidjo

Angelique Kidjo - Orubaba songtekst

Je score:


Alé, alé

Alé, alé

Alé, alé

Alé, alé


N'kan kpataki ni

Oru foun Enyian

Ma ché béru

Orèmi ninou okounkoun

T'oba fe d'agba

Wo ninou ayé yi

Ma ché bêru

Oremi ninoun okounkoun


Orubaba, orubaba

Mandjè kin m'béru l'ayé yi o

l'ayé l'ayé


Ninoun oru ni

Awon omodé n'dagba

Ninoun oru ni

Awa ma ro n'kan wo

llè bamon n'ko?

Ma ché cholè mon

Igabdoun m'bè l'onan


Orubaba, orubaba

Mandjè kin m'béru l'ayé yi o

l'ayé l'ayé

l'ayé l'ayé


Orubaba, orubaba, orubaba

Orubaba, orubaba, orubaba



Vind dit lied op:
bol.com
amazon.com

Copyrights:

Auteur: ?

Componist: ?

Publisher: ?

Details:

Taal: Servisch

Deel je mening

Dit formulier wordt beschermd door reCAPTCHA en de Google Privacy Policy en Servicevoorwaarden zijn daarbij van toepassing.

0 Reacties gevonden